Orin Dafidi 53:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọrun bojú wo àwọn ọmọ eniyan láti ọ̀run wá,ó ń wò ó bí àwọn kan bá wà tí òye yé,àní, bí àwọn kan bá wà tí ń wá Ọlọrun.

Orin Dafidi 53

Orin Dafidi 53:1-6