Orin Dafidi 43:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìwọ ọkàn mi, kí ló dé tí o fi rẹ̀wẹ̀sì?Kí ló dé tí ara rẹ kò fi balẹ̀ ninu mi?Gbẹ́kẹ̀ rẹ lé Ọlọrun; nítorí pé n óo tún yìn ín,olùrànlọ́wọ́ mi ati Ọlọrun mi.

Orin Dafidi 43

Orin Dafidi 43:1-5