Orin Dafidi 43:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà náà ni n óo lọ sí ibi pẹpẹ Ọlọrun,àní, sọ́dọ̀ Ọlọrun, ayọ̀ ńlá mi.Èmi óo sì yìn ọ́ pẹlu hapu,Ọlọrun, Ọlọrun mi.

Orin Dafidi 43

Orin Dafidi 43:1-5