Orin Dafidi 44:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọrun, a ti fi etí wa gbọ́,àwọn baba wa sì ti sọ fún wa,nípa àwọn ohun tí o ṣe nígbà ayé wọn,àní, ní ayé àtijọ́:

Orin Dafidi 44

Orin Dafidi 44:1-8