Orin Dafidi 40:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó fi orin titun sí mi lẹ́nu,àní, orin ìyìn sí Ọlọrun wa.Ọ̀pọ̀ yóo rí i, ẹ̀rù óo bà wọ́n,wọn óo sì gbẹ́kẹ̀lé OLUWA.

Orin Dafidi 40

Orin Dafidi 40:2-12