Orin Dafidi 40:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó fà mí jáde láti inú ọ̀gbun ìparun,láti inú kòtò tí ó kún fún ẹrọ̀fọ̀;ó gbé mi kalẹ̀ lórí àpáta,ó sì fi ẹsẹ̀ mi tẹlẹ̀.

Orin Dafidi 40

Orin Dafidi 40:1-5