Orin Dafidi 40:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ayọ̀ ń bẹ fún ẹni náà,tí ó gbẹ́kẹ̀ rẹ̀ lé OLUWA,tí kò bá àwọn onigbeeraga rìn,àwọn tí wọn ti ṣìnà lọ sọ́dọ̀ àwọn oriṣa.

Orin Dafidi 40

Orin Dafidi 40:1-13