Orin Dafidi 40:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí gbogbo àwọn tí ń wá ọ máa yọ̀,kí inú wọn sì máa dùn nítorí rẹ;kí àwọn tí ó fẹ́ràn ìgbàlà rẹmáa wí nígbà gbogbo pé, “OLUWA tóbi!”

Orin Dafidi 40

Orin Dafidi 40:14-17