Orin Dafidi 40:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní tèmi, olùpọ́njú ati aláìní ni mí;ṣugbọn Oluwa kò gbàgbé mi.Ìwọ ni olùrànlọ́wọ́ ati olùgbàlà mi,má pẹ́, Ọlọrun mi.

Orin Dafidi 40

Orin Dafidi 40:13-17