Orin Dafidi 40:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Jẹ́ kí jìnnìjìnnì bò wọ́n,kí wọ́n sì gba èrè ìtìjú,àní, àwọn tí ń ṣe jàgínní mi.

Orin Dafidi 40

Orin Dafidi 40:7-17