Orin Dafidi 40:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Jẹ́ kí ojú ti gbogbo àwọn tí wọ́n fẹ́gba ẹ̀mí mi,kí ìdàrúdàpọ̀ bá gbogbo wọn patapata,jẹ́ kí á lé àwọn tí ń wá ìpalára mi pada sẹ́yìn,kí wọ́n sì tẹ́.

Orin Dafidi 40

Orin Dafidi 40:9-17