Orin Dafidi 37:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí pé a óo pa àwọn eniyan burúkú run;ṣugbọn àwọn tí ó gbẹ́kẹ̀lé OLUWAni yóo jogún ilẹ̀ náà.

Orin Dafidi 37

Orin Dafidi 37:5-10