Orin Dafidi 37:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ fún eniyan burúkú ní ìgbà díẹ̀ sí i, yóo pòórá;ẹ̀ báà wá a títí ní ààyè rẹ̀, kò ní sí níbẹ̀.

Orin Dafidi 37

Orin Dafidi 37:5-19