Orin Dafidi 37:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Yẹra fún ibinu; sì yàgò fún ìrúnú.Má gbé ara rẹ lọ́kàn gbóná; ibi ni àyọrísí rẹ̀.

Orin Dafidi 37

Orin Dafidi 37:1-15