Orin Dafidi 37:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn àwọn eniyan burúkú yóo ṣègbé;àwọn ọ̀tá OLUWA yóo pòórá bí ẹwà ewékowọn óo parẹ́ bí èéfín tí í parẹ́.

Orin Dafidi 37

Orin Dafidi 37:15-24