Orin Dafidi 37:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí eniyan burúkú bá yá owó, kò ní san;ṣugbọn ẹni rere ní ojú àánú, ó sì lawọ́.

Orin Dafidi 37

Orin Dafidi 37:18-22