Orin Dafidi 27:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ogun tilẹ̀ dó tì míàyà mi kò ní já.Bí wọ́n tilẹ̀ gbé ogun wá bá mi,sibẹ, ọkàn mi kò ní mì.

Orin Dafidi 27

Orin Dafidi 27:2-10