Orin Dafidi 27:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí àwọn aṣebi bá ń gbógun bọ̀ wá bá mi,tí wọ́n fẹ́ pa mí,àwọn alátakò ati àwọn ọ̀tá mi,wọn óo kọsẹ̀, wọn óo sì ṣubú.

Orin Dafidi 27

Orin Dafidi 27:1-4