Orin Dafidi 27:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ohun kan ni mo ti tọrọ lọ́dọ̀ OLUWA,òun ni n óo sì máa lépa:Kí n lè máa gbé inú ilé OLUWAní gbogbo ọjọ́ ayé mi,kí n lè máa wo ẹwà OLUWA,kí n sì máa fi tọkàntọkàn sìn ín ninu tẹmpili rẹ̀.

Orin Dafidi 27

Orin Dafidi 27:3-11