Orin Dafidi 24:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹni tí ọwọ́ rẹ̀ mọ́, tí inú rẹ̀ sì funfun,tí kò gbẹ́kẹ̀lé oriṣa lásánlàsàn,tí kò sì búra èké.

Orin Dafidi 24

Orin Dafidi 24:1-7