Orin Dafidi 24:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ta ló lè gun orí òkè OLUWA lọ?Ta ló sì lè dúró ninu ibi mímọ́ rẹ̀?

Orin Dafidi 24

Orin Dafidi 24:1-4