Orin Dafidi 22:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn kòkòrò lásán ni mí, n kì í ṣe eniyan;ayé kẹ́gàn mi, gbogbo eniyan sì ń fi mí ṣe ẹlẹ́yà.

Orin Dafidi 22

Orin Dafidi 22:1-11