Orin Dafidi 22:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo àwọn tí ó rí mi ní ń fi mí ṣe yẹ̀yẹ́;wọ́n ń yọ ṣùtì sí mi;wọ́n sì ń mi orí pé,

Orin Dafidi 22

Orin Dafidi 22:1-17