Orin Dafidi 22:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n kígbe pè ọ́, o sì gbà wọ́n;ìwọ ni wọ́n gbẹ́kẹ̀lé, ojú kò sì tì wọ́n.

Orin Dafidi 22

Orin Dafidi 22:1-11