Orin Dafidi 144:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ìgbà èwe àwọn ọdọmọkunrin wa,jẹ́ kí wọ́n dàbí igi tí a gbìn tí ó dàgbà,kí àwọn ọdọmọbinrin wa dàbí òpó igun ilé,tí a ṣiṣẹ́ ọnà sí bíi ti ààfin ọba.

Orin Dafidi 144

Orin Dafidi 144:2-15