Orin Dafidi 144:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbà mí lọ́wọ́ idà ìkà,gbà mí lọ́wọ́ àwọn àjèjì,tí ẹnu wọ́n kún fún irọ́,tí ọwọ́ ọ̀tún wọn sì kún fún èké.

Orin Dafidi 144

Orin Dafidi 144:10-13