Orin Dafidi 144:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí àká wa kún fún oniruuru oúnjẹ,kí àwọn aguntan wa bí ẹgbẹẹgbẹrun,àní, ẹgbẹẹgbaarun ninu pápá oko wa.

Orin Dafidi 144

Orin Dafidi 144:5-15