Orin Dafidi 138:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí mo tilẹ̀ wà ninu ìpọ́njú,sibẹ, o dá mi sí;o dojú ìjà kọ ibinu àwọn ọ̀tá mi,o sì fi ọwọ́ agbára rẹ gbà mí.

Orin Dafidi 138

Orin Dafidi 138:3-8