Orin Dafidi 138:8 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA yóo mú ìfẹ́ rẹ̀ ṣẹ lórí mi,OLUWA, ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ wà títí lae.Má kọ iṣẹ́ ọwọ́ rẹ sílẹ̀.

Orin Dafidi 138

Orin Dafidi 138:2-8