Orin Dafidi 138:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé OLUWA ga lọ́lá,ó ka àwọn onírẹ̀lẹ̀ sí,ṣugbọn ó mọ àwọn onigbeeraga lókèèrè.

Orin Dafidi 138

Orin Dafidi 138:1-7