Orin Dafidi 134:2-3 BIBELI MIMỌ (BM)

2. Ẹ gbé ọwọ́ yín sókè, kí ẹ gbadura ninu ilé mímọ́ rẹ̀,kí ẹ sì yin OLUWA.

3. Kí OLUWA tí ó dá ọ̀run ati ayébukun yín láti Sioni wá.

Orin Dafidi 134