Orin Dafidi 132:16 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo gbé ẹ̀wù ìgbàlà wọ àwọn alufaa rẹ̀,àwọn eniyan mímọ́ rẹ̀ yóo sì kọrin ayọ̀.

Orin Dafidi 132

Orin Dafidi 132:8-18