Orin Dafidi 13:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Títí di ìgbà wo ni ọkàn mi yóo gbọgbẹ́tí ìbànújẹ́ yóo gba ọkàn mi kan, ní gbogbo ìgbà?Títí di ìgbà wo ni àwọn ọ̀tá mi yóo máa yọ̀ mí?

Orin Dafidi 13

Orin Dafidi 13:1-6