Orin Dafidi 13:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Bojúwò mí, kí o sì dá mi lóhùn, OLUWA, Ọlọrun mi.Tan ìmọ́lẹ̀ sí ojú mi, kí n má baà sun oorun ikú.

Orin Dafidi 13

Orin Dafidi 13:2-6