Orin Dafidi 13:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Yóo ti pẹ́ tó, OLUWA?Ṣé o óo wá gbàgbé mi laelae ni?Títí di ìgbà wo ni o óo fi ojú pamọ́ fún mi?

Orin Dafidi 13

Orin Dafidi 13:1-6