Orin Dafidi 127:3-5 BIBELI MIMỌ (BM)

3. Wò ó! Ẹ̀bùn OLUWA ni ọmọ;òun ní fi oyún inú ṣìkẹ́ eniyan.

4. Bí ọfà ti rí lọ́wọ́ jagunjagun,bẹ́ẹ̀ ni àwọn ọmọ ìgbà òwúrọ̀ ẹni.

5. Ayọ̀ ń bẹ fun ẹni tí apó rẹ̀ kún fún wọn.Ojú kò ní tì í nígbà tí ó bá ń bá àwọn ọ̀tá rẹ̀ rojọ́ lẹ́nu bodè.

Orin Dafidi 127