Ayọ̀ ń bẹ fun ẹni tí apó rẹ̀ kún fún wọn.Ojú kò ní tì í nígbà tí ó bá ń bá àwọn ọ̀tá rẹ̀ rojọ́ lẹ́nu bodè.