Asán ni kí á jí ní òwúrọ̀ kutukutu,kí á tún pẹ́ títí kí á tó sùn.Asán ni kí á máa fi làálàá wá oúnjẹ;nítorí pé OLUWA a máa fún àwọn àyànfẹ́ rẹ̀ ní oorun sùn.