Bí OLUWA kò bá kọ́ ilé,asán ni wahala àwọn tí ń kọ́ ọ.Bí OLUWA kò bá ṣọ́ ìlú,asán ni àìsùn àwọn aṣọ́de.