Orin Dafidi 120:5-7 BIBELI MIMỌ (BM)

5. Mo gbé! Nítorí pé mo dàbí àlejò tó wọ̀ ní Meṣeki,tí ń gbé ààrin àwọn àgọ́ Kedari.

6. Ó pẹ́ jù tí mo tí ń bá àwọn tí ó kórìíra alaafia gbé.

7. Alaafia ni èmi fẹ́,ṣugbọn nígbà tí mo bá sọ̀rọ̀, ìjà ṣá ni tiwọn.

Orin Dafidi 120