Orin Dafidi 119:176 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo ti ṣìnà bí aguntan tó sọnù;wá èmi, iranṣẹ rẹ, rí,nítorí pé n kò gbàgbé òfin rẹ.

Orin Dafidi 119

Orin Dafidi 119:173-176