Orin Dafidi 120:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo gbé! Nítorí pé mo dàbí àlejò tó wọ̀ ní Meṣeki,tí ń gbé ààrin àwọn àgọ́ Kedari.

Orin Dafidi 120

Orin Dafidi 120:1-7