Orin Dafidi 102:27-28 BIBELI MIMỌ (BM)

27. Ṣugbọn ìwọ wà bákan náà,ọjọ́ ayé rẹ kò sì lópin.

28. Ọmọ àwọn iranṣẹ rẹ yóo ní ibùgbé;bẹ́ẹ̀ ni arọmọdọmọ wọn yóo fẹsẹ̀ múlẹ̀ níwájú rẹ.

Orin Dafidi 102