Orin Dafidi 102:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọmọ àwọn iranṣẹ rẹ yóo ní ibùgbé;bẹ́ẹ̀ ni arọmọdọmọ wọn yóo fẹsẹ̀ múlẹ̀ níwájú rẹ.

Orin Dafidi 102

Orin Dafidi 102:19-28