Orin Dafidi 101:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ojoojumọ ni n óo máa pa àwọn eniyan burúkú run ní ilẹ̀ náà,n óo lé gbogbo àwọn aṣebi kúrò ninu ìlú OLUWA.

Orin Dafidi 101

Orin Dafidi 101:2-8