Orin Dafidi 10:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Eniyan burúkú kò wá Ọlọrun, nítorí ìgbéraga ọkàn rẹ̀,kò tilẹ̀ sí ààyè fún Ọlọrun ninu gbogbo ìrònú rẹ̀.

Orin Dafidi 10

Orin Dafidi 10:1-6