Orin Dafidi 10:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Eniyan burúkú ń fọ́nnu lórí ìfẹ́ ọkàn rẹ̀,Ó ń bu ọlá fún wọ̀bìà, ó sì ń kẹ́gàn OLUWA.

Orin Dafidi 10

Orin Dafidi 10:1-11