Orin Dafidi 10:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà gbogbo ni nǹkan ń dára fún un.Ìdájọ́ rẹ, Ọlọrun, ga pupọ, ó ju òye rẹ̀ lọ;ó ń yọ ṣùtì ètè sí gbogbo àwọn ọ̀tá rẹ̀.

Orin Dafidi 10

Orin Dafidi 10:1-15