Nọmba 22:37 BIBELI MIMỌ (BM)

Balaki wí fún un pé, “Kí ló dé tí o kò fi wá nígbà tí mo ranṣẹ sí ọ lákọ̀ọ́kọ́? Ṣé o rò pé n kò lè sọ ọ́ di ẹni pataki ni?”

Nọmba 22

Nọmba 22:29-41