Nọmba 22:36 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Balaki gbọ́ pé Balaamu ń bọ̀, ó jáde lọ pàdé rẹ̀ ní ìlú Moabu tí ó wà létí odò Arinoni ní ààlà ilẹ̀ Moabu.

Nọmba 22

Nọmba 22:26-40